DOKITA BE SOMI LATORI AFARA THIRD MAIN LAND BRIDGE, NI ILU EKO
Oro di bo o lo yago ni irole ojo isinmi to koja ni igba ti Onisegun Oyinbo Dokita kan dede da Direba re duro to si silekun oko jiipu Nisan to ni namba idako moo LND 476EE to si be somi Osa .Gege bi awon ti Isele ohun se oju won se so , won ni Direba so pe , fonu oga dun ti oga si gbe e ipe yi sugbon leyin ipe n se ni Oga pase pe ki ohun duro ati pe ohun fe wo ikankan , a fi jua ninu Osa !Ah ! E emo ! ni igbe ti gbogbo awon ero ti won fe woko ti Isele yi soju won nke e . Iroyin fi towa leti wipe lati ile ijosin ni arakunrin naa tin bo wa. Lesekese ni awon Olopa lati Adeniji Adele mu Awako okunrin Dokita yi ati jiipu re lo si Ago won fun iwadi . Amo o , awon Ajo to n ri si isele pajawiri ( LASEMA) ati awon Panapana pelu iranwo awon apeja n wa oku arakunrin naa titi di asiko ti a n ko iroyin yi Jo o .
No comments:
Post a Comment