OWO OFIN TI TE AYEDERU OLOPA KAN TI ON FI IPA GBA RI BA LOWO AWON ARA ILU
Leyin opolopo odun ti Olaiwola Animashaun tin fi eru gba ibukun. Owo ofin papa mu, won ni bi iro ba lo logun odun, ijokan ni otito a telee.
Ogbeni Olaiwola ti oje omo odun merin le logbon yi ti pe ara re ni olopa fun awon aniyan kaakiri, ti osi tun fi ipa gba owo lowo awon ara ilu, sugbon owo awon olopa ti baa bayi. I wadi fihan wipe otin se ise buruku yi tipe. Ofe lo bere ise re ni ojo ti owo o palaba re se gi, ni abe afara a tii Ojuelegba, sugbon ni igba ti ori oko awon olopa, ni oba fi ese fe. Sugbon won to pinpin re de Thomas Animashaun Street, ni Aguda Surulere.
Awon ara adugbo naa fi to akoroyin wa leti wipe gbogbo igba ni arakunrin naa man fi ipa gba owo lowo awon awako ati olokada ni agbegbe surulere, ojuelegba, stadium ati awon agbegbe ree.
Agbenuso awon olopa kan ni o so wipe ohun wa lara awon ti o to pin pin arakunrin yi de ile re, ti won si iri kaadi idanimo ti ijo ipinle eko, ada ati ero ibani soro o ti awon olopa. Alukoro fun awon olopa tii ipinle eko ti so wipe yio fi oju ba ile ejo.
No comments:
Post a Comment